Ìfihàn 13:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 A gbà á láyè pé kó fún ère ẹranko náà ní èémí,* kí ère ẹranko náà lè sọ̀rọ̀, kó sì mú kí wọ́n pa gbogbo àwọn tó kọ̀ láti jọ́sìn ère ẹranko náà. Ìfihàn 19:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 A sì mú ẹranko náà pẹ̀lú wòlíì èké+ tó ṣe àwọn iṣẹ́ àmì níwájú rẹ̀, èyí tó fi ṣi àwọn tó gba àmì ẹranko náà+ lọ́nà àti àwọn tó jọ́sìn ère rẹ̀.+ A ju àwọn méjèèjì láàyè sínú adágún iná tó ń jó, tí a fi imí ọjọ́ sí.+
15 A gbà á láyè pé kó fún ère ẹranko náà ní èémí,* kí ère ẹranko náà lè sọ̀rọ̀, kó sì mú kí wọ́n pa gbogbo àwọn tó kọ̀ láti jọ́sìn ère ẹranko náà.
20 A sì mú ẹranko náà pẹ̀lú wòlíì èké+ tó ṣe àwọn iṣẹ́ àmì níwájú rẹ̀, èyí tó fi ṣi àwọn tó gba àmì ẹranko náà+ lọ́nà àti àwọn tó jọ́sìn ère rẹ̀.+ A ju àwọn méjèèjì láàyè sínú adágún iná tó ń jó, tí a fi imí ọjọ́ sí.+