1 Pétérù 4:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Inú yín máa dùn tí wọ́n bá ń gàn yín* nítorí orúkọ Kristi,+ torí pé ẹ̀mí ògo, àní ẹ̀mí Ọlọ́run, ti bà lé yín.
14 Inú yín máa dùn tí wọ́n bá ń gàn yín* nítorí orúkọ Kristi,+ torí pé ẹ̀mí ògo, àní ẹ̀mí Ọlọ́run, ti bà lé yín.