Àìsáyà 21:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wo ohun tó ń bọ̀: Àwọn ọkùnrin wà nínú kẹ̀kẹ́ ogun tí wọ́n so àwọn ẹṣin mọ́!”+ Ó wá sọ pé: “Ó ti ṣubú! Bábílónì ti ṣubú!+ Gbogbo ère gbígbẹ́ àwọn ọlọ́run rẹ̀ ló ti fọ́ sílẹ̀ túútúú!”+ Jeremáyà 51:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Lójijì, Bábílónì ṣubú, ó sì fọ́.+ Ẹ pohùn réré ẹkún fún un! + Ẹ fún un ní básámù nítorí ìrora rẹ̀; bóyá ara rẹ̀ máa yá.” Ìfihàn 14:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Áńgẹ́lì kejì tẹ̀ lé e, ó ń sọ pé: “Ó ti ṣubú! Bábílónì Ńlá+ ti ṣubú,+ ẹni tó mú kí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè mu nínú wáìnì ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́* ti ìṣekúṣe* rẹ̀!”+
9 Wo ohun tó ń bọ̀: Àwọn ọkùnrin wà nínú kẹ̀kẹ́ ogun tí wọ́n so àwọn ẹṣin mọ́!”+ Ó wá sọ pé: “Ó ti ṣubú! Bábílónì ti ṣubú!+ Gbogbo ère gbígbẹ́ àwọn ọlọ́run rẹ̀ ló ti fọ́ sílẹ̀ túútúú!”+
8 Lójijì, Bábílónì ṣubú, ó sì fọ́.+ Ẹ pohùn réré ẹkún fún un! + Ẹ fún un ní básámù nítorí ìrora rẹ̀; bóyá ara rẹ̀ máa yá.”
8 Áńgẹ́lì kejì tẹ̀ lé e, ó ń sọ pé: “Ó ti ṣubú! Bábílónì Ńlá+ ti ṣubú,+ ẹni tó mú kí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè mu nínú wáìnì ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́* ti ìṣekúṣe* rẹ̀!”+