Ìfihàn 16:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ní tòótọ́, wọ́n jẹ́ àwọn ọ̀rọ̀ tí àwọn ẹ̀mí èṣù mí sí, wọ́n ń ṣe àwọn iṣẹ́ àmì,+ wọ́n sì lọ sọ́dọ̀ àwọn ọba gbogbo ilẹ̀ ayé tí à ń gbé, láti kó wọn jọ sí ogun+ ọjọ́ ńlá Ọlọ́run Olódùmarè.+ Ìfihàn 16:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Wọ́n sì kó wọn jọ sí ibi tí wọ́n ń pè ní Amágẹ́dọ́nì*+ lédè Hébérù.
14 Ní tòótọ́, wọ́n jẹ́ àwọn ọ̀rọ̀ tí àwọn ẹ̀mí èṣù mí sí, wọ́n ń ṣe àwọn iṣẹ́ àmì,+ wọ́n sì lọ sọ́dọ̀ àwọn ọba gbogbo ilẹ̀ ayé tí à ń gbé, láti kó wọn jọ sí ogun+ ọjọ́ ńlá Ọlọ́run Olódùmarè.+