Ìfihàn 14:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Lẹ́yìn náà, wò ó! mo rí Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà+ tó dúró lórí Òkè Síónì,+ àwọn ọ̀kẹ́ méje ó lé ẹgbàajì+ (144,000) wà pẹ̀lú rẹ̀, a kọ orúkọ rẹ̀ àti orúkọ Baba+ rẹ̀ sí iwájú orí wọn.
14 Lẹ́yìn náà, wò ó! mo rí Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà+ tó dúró lórí Òkè Síónì,+ àwọn ọ̀kẹ́ méje ó lé ẹgbàajì+ (144,000) wà pẹ̀lú rẹ̀, a kọ orúkọ rẹ̀ àti orúkọ Baba+ rẹ̀ sí iwájú orí wọn.