Sáàmù 117 Ẹ yin Jèhófà, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè;+Ẹ gbé e ga, gbogbo ẹ̀yin èèyàn.*+ 2 Nítorí ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ tó ní sí wa pọ̀ gan-an;+Òtítọ́+ Jèhófà wà títí láé.+ Ẹ yin Jáà!*+