Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ọbadáyà ỌBADÁYÀ OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ Ọlọ́run yóò rẹ Édómù agbéraga wálẹ̀ (1-9) Édómù hùwà ipá sí Jékọ́bù (10-14) Ọjọ́ tí Jèhófà yóò gbéjà ko gbogbo orílẹ̀-èdè (15, 16) Ilé Jékọ́bù yóò pa dà sí àyè rẹ̀ (17-21) Jékọ́bù yóò pa Édómù run (18) Ipò ọba yóò di ti Jèhófà (21)