Iwo Yoo Ha Gba Ìkésíni Bi?
Ani ninu ayé onidaamu yii, iwọ lè jere ayọ lati inu ìmọ̀ Bibeli pipeye nipa Ọlọrun, Ijọba rẹ̀, ati ète agbayanu rẹ̀ fun araye. Bi iwọ yoo bá fẹ́ lati gba isọfunni sii tabi bi iwọ yoo ba fẹ́ ki ẹnikan ké si ọ lati dari ikẹkọọ Bibeli inu ile lọfẹẹ pẹlu rẹ, jọwọ kọwe si Watch Tower, P.M.B. 1090, Benin City, Edo State, tabi si adirẹsi ti ó ṣe wẹ́kú ti a tò si oju-iwe 2.