Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
JULY 2016
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́: AUGUST 29–SEPTEMBER 25, 2016
© 2016 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
DOMINICAN REPUBLIC
Etíkun Las Terrenas rèé níbi tí aṣáájú-ọ̀nà àkànṣe kan ti ń wàásù fún ọkùnrin kan tó lọ ká àgbọn
IYE AKÉDE
37,536
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
69,892
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2015)
120,103
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ fi ọrẹ ṣètìlẹyìn, jọ̀wọ́ lọ sórí www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, tá a fi àkọtọ́ tó bóde mu kọ, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.