Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
SEPTEMBER 2017
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: OCTOBER 23–NOVEMBER 26, 2017
© 2017 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
EL SALVADOR
Àwọn tọkọtaya méjì fi kẹ̀kẹ́ tó ṣeé tì kiri pàtẹ àwọn ìwé wa, wọ́n sì ń wàásù níbi térò pọ̀ sí. Iwájú ọ̀kan lára àwọn ibi ìtajà tó tóbi jù nílùú San Salvador ni wọ́n dúró sí
IYE AKÉDE
41,084
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
42,813
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2016)
92,606
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì wa www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.