Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG
TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?
Apá tó rọ̀ tí Octopus ní ti jẹ́ káwọn ẹnjiníà tó ń ṣe rọ́bọ́ọ̀tì ṣe àwọn irinṣẹ́ kan. Àwọn irinṣẹ́ yìí ló máa ń jẹ́ káwọn dókítà ráyè ṣiṣẹ́ abẹ láwọn ibi kọ́lọ́fín ara láìsí pé wọ́n ń fi abẹ la aláìsàn nílàkulà.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÌMỌ̀ SÁYẸ́ǸSÌ ÀTI BÍBÉLÌ > TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?
BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ
Ó dá Óscar lójú pé òun ò bá ti kú tí kì í bá ṣe ti Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tó yí òun pa dà. Kí ló mú kí ẹnì kan tó wá láti El Salvador, tó sì jẹ́ ọmọ ìta tẹ́lẹ̀ yí ìgbésí ayé rẹ̀ pa dà?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀLÀÁFÍÀ ÀTI AYỌ̀ > BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ.