April 11 Sí 17
JÓÒBÙ 21-27
Orin 83 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Jóòbù Kò Fàyè Gba Èrò Òdì”: (10 min.)
Job 22:2-7—Élífásì dá lórí èrò èké àti èrò tara rẹ̀ (w06 3/15 ojú ìwé 15 ìpínrọ̀ 7; w05 9/15 ojú ìwé 26 àti 27; w95 2/15 ojú ìwé 27 ìpínrọ̀ 6)
Job 25:4, 5—Ọ̀rọ̀ tí kì í ṣe òótọ́ ni Bílídádì sọ (w05 9/15 ojú ìwé 26 àti 27)
Job 27:5, 6—Jóòbù kò jẹ́ kí àwọn èèyàn mú kó máa rò pé òun ò pa ìwà títọ́ òun mọ́ (w09 8/15 ojú ìwé 4 ìpínrọ̀ 8; w06 3/15 ojú ìwé 15 ìpínrọ̀ 9)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Job 24:2—Kí nìdí tí sísún ààlà sẹ́yìn fí jẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ tó burú jáì (it-1-E ojú ìwé 360)
Job 26:7—Kí nìdí tí ohun tí Jóòbù sọ nípa ayé fi ṣe pàtàkì? (w15 6/1 ojú ìwé 5 ìpínrọ̀ 4; w11 7/1 ojú ìwé 26 ìpínrọ̀ 2 sí 5)
Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?
Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?
Bíbélì Kíkà: Job 27:1-23 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: Àwòrán iwájú ìwé ìròyìn g16.2—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá pa dà wá. (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
Ìpadàbẹ̀wò: Àwòrán iwájú ìwé ìròyìn g16.2—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá tún pa dà wá. (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: bh ojú ìwé 145 ìpínrọ̀ 3 àti 4 (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Bó O Ṣe Lè Borí Ẹni Tó Ń Halẹ̀ Mọ́ Ẹ Láì Bá A Jà: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò eré ojú pátákó tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Bó O Ṣe Lè Borí Ẹni Tó Ń Halẹ̀ Mọ́ Ẹ Láì Bá A Jà. (Lọ sí jw.org/yo, kó o sì wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́.) Lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò àwọn ìbéèrè yìí: Kí nìdí tí wọ́n fi lè máa halẹ̀ mọ́ ẹnì kan? Ìpalára wo ni híhalẹ̀ mọ́ni máa ń fà? Báwo lo ṣe lè borí ẹni tó ń halẹ̀ mọ́ ẹ tàbí kó o yẹra fún un? Ta lo lè sọ fún tí wọ́n bá ń halẹ̀ mọ́ ẹ? Tọ́ka sí orí 14 ìwé Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè, Apá 2.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: ia orí 13 ìpínrọ̀ 1 sí 12 (30 min..)
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 23 àti Àdúrà