KÓLÓSÈ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
Ìkíni (1, 2)
Pọ́ọ̀lù dúpẹ́ nítorí ìgbàgbọ́ àwọn ará Kólósè (3-8)
Àdúrà pé kí wọ́n máa dàgbà sí i nípa tẹ̀mí (9-12)
Ipa àrà ọ̀tọ̀ tí Kristi kó (13-23)
Iṣẹ́ àṣekára tí Pọ́ọ̀lù ṣe fún ìjọ (24-29)
2
Kristi, àṣírí mímọ́ Ọlọ́run (1-5)
Ẹ máa ṣọ́ra fún àwọn ẹlẹ́tàn (6-15)
Ohun gidi náà ni Kristi (16-23)
3
4
Ìmọ̀ràn fún àwọn ọ̀gá (1)
“Ẹ tẹra mọ́ àdúrà gbígbà” (2-4)
Ẹ máa fi ọgbọ́n bá àwọn tó wà lóde lò (5, 6)
Ìkíni tó fi parí ọ̀rọ̀ rẹ̀ (7-18)