ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 142-150
“Jèhófà Tóbi, Ó sì Yẹ fún Ìyìn Gidigidi”
Dáfídì rí i pé títóbi Jèhófà kò ní ààlà, ìyẹn sì mú kó sọ pé òun á máa yin Jèhófà títí ayé
Bíi ti Dáfídì, gbogbo ìgbà làwọn olóòótọ́ ìránṣẹ́ Jèhófà máa ń sọ̀rọ̀ nípa agbára ńlá rẹ̀
Ó dá Dáfídì lójú pé ó máa ń wu Jèhófà láti ṣìkẹ́ àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ àti pé ó lágbára láti ṣe bẹ́ẹ̀