ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁÀKÙ 1-2
“A Dárí Àwọn Ẹ̀ṣẹ̀ Rẹ Jì”
Ẹ̀kọ́ wo ni a rí kọ́ nínú iṣẹ́ ìyanu yìí?
Ẹ̀ṣẹ̀ tá a jogún ló jẹ́ ká máa ṣàìsàn
Jésù ní agbára láti dárí ẹ̀ṣẹ̀ jini àti láti mú àwọn aláìsàn lára dá
Nínú Ìjọba Ọlọ́run, Jésù máa mú àìpé àti àìsàn kúrò títí láé
Báwo ni Máàkù 2:5-12 ṣe lè ràn mí lọ́wọ́ láti fara dà á tí mo bá ń ṣàìsàn?