Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Tún fi Jónà 2:2, 4-9 wé Sáàmù 18:6; 31:22; 30:3; 142:3; 31:6; àti 3:8. A to àwọn sáàmù yìí níbàámu pẹ̀lú bí Jónà ṣe mẹ́nu kan àwọn ọ̀rọ̀ tó wà nínú wọn.