Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Àwọn ìwé ńlá míì tá a fi ń kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, tó ti ran àwọn akéde lọ́wọ́ láti kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ òtítọ́ ni Duru Ọlọrun (ọdún 1921 la tẹ̀ ẹ́ lédè Gẹ̀ẹ́sì), Jẹki Ọlọrun Jẹ Olõtọ (ọdún 1946 la tẹ̀ ẹ́ lédè Gẹ̀ẹ́sì, ó jáde ní Yorùbá ní 1962), Iwọ Le Walaaye Titilae ninu Paradise lori Ilẹ Aye (ọdún 1982 la tẹ̀ ẹ́ lédè Gẹ̀ẹ́sì, ó jáde ní Yorùbá ní 1983) àti Ìmọ̀ Tí Ń Sinni Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun (ọdún 1995 la tẹ̀ ẹ́).