Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé c Èyí wáyé ní òpin ọdún mẹ́ta àtààbọ̀ tá a fi fún àwọn Júù nípa tara láǹfààní láti di apá kan orílẹ̀-èdè tẹ̀mí tuntun náà. Bíbélì ti sọ̀rọ̀ nípa èyí nínú àsọtẹ́lẹ̀ àádọ́rin [70] ọ̀sẹ̀ ti ọdún.—Dán. 9:27.