Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Nígbà yẹn, Jèhófà gbà wọ́n láyé láti fẹ́ ju ìyàwó kan lọ tàbí kí wọ́n ní àlè, àmọ́ nígbà tó yá Jèhófà fún Jésù Kristi láṣẹ pé kó dá ìgbéyàwó pa dà sí bó ṣe wà ní ìbẹ̀rẹ̀ nínú ọgbà Édẹ́nì, ìyẹn ọkọ kan aya kan.—Jẹ́nẹ́sísì 2:24; Mátíù 19:3-9.