Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Wọn ò bí ọkàn tútù mọ́ ẹnikẹ́ni, àfi kéèyàn kọ́ ọ. Ó lè rọrùn láti jẹ́ ọlọ́kàn tútù tí nǹkan bá dà wá pọ̀ pẹ̀lú àwọn tó lẹ́mìí àlàáfíà, àmọ́ ó lè má fi bẹ́ẹ̀ rọrùn tó bá jẹ́ pé àwọn agbéraga la bá da nǹkan pọ̀. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò àwọn nǹkan tó yẹ ká borí ká tó lè jẹ́ ọlọ́kàn tútù.