Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Àwòrán àti Fídíò - Nọ́ńbà A ṣèwádìí tó jinlẹ̀ ká tó ya àwọn àwòrán, ká sì tó ṣe àwọn fídíò tó wà nínú àkójọ yìí. Síbẹ̀, ó lè jẹ́ apá kan ṣoṣo lára àwọn ohun tó ṣeé ṣe kó ṣẹlẹ̀ la gbé yọ nínú àwọn àwòrán náà.