November Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé, November 2016 Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò November 7-13 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÒWE 27-31 Bíbélì Sọ Ohun Tí Ìyàwó Tó Dáńgájíá Máa Ń Ṣe MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI ‘Ẹni Mímọ̀ Ni Ọkọ Rẹ̀ Jẹ́ Ní Àwọn Ẹnubodè’ November 14 sí 20 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ONÍWÀÁSÙ 1-6 Gbádùn Gbogbo Iṣẹ́ Àṣekára Rẹ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Bá A Ṣe Máa Lo Ìwé Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa? November 21 sí 27 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ONÍWÀÁSÙ 7-12 “Rántí Ẹlẹ́dàá Rẹ Atóbilọ́lá . . . Ní Àwọn Ọjọ́ Tí O Wà Ní Ọ̀dọ́kùnrin” MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Ẹ Má Ṣe Fàkókò Ṣòfò Láti Wọnú “Ilẹ̀kùn Ńlá” November 28 sí December 4 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ORIN SÓLÓMỌ́NÌ 1-8 Ọmọbìnrin Ṣúlámáítì Jẹ́ Àpẹẹrẹ Rere Tá A Lè Tẹ̀ Lé