Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
ORÍ OJÚ ÌWÉ
Ọ̀RỌ̀ ÌṢÁÁJÚ
1. “Ẹ Lọ, Kí Ẹ Máa Sọ Àwọn Èèyàn . . . Di Ọmọ Ẹ̀yìn” 6
APÁ 1—“Ẹ Ti Fi Ẹ̀kọ́ Yín Kún Jerúsálẹ́mù”
3. Wọ́n “Kún fún Ẹ̀mí Mímọ́” 21
4. ‘Àwọn Èèyàn Tí Ò Kàwé àti Gbáàtúù’ 28
5. “A Gbọ́dọ̀ Ṣègbọràn sí Ọlọ́run Gẹ́gẹ́ Bí Alákòóso” 37
APÁ 2—“Wọ́n Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Ṣe Inúnibíni Tó Lágbára sí Ìjọ”
6. Sítéfánù “Kún fún Oore Ọlọ́run àti Agbára” 45
7. Fílípì Kéde “Ìhìn Rere Nípa Jésù” 52
8. Ìjọ “Wọnú Àkókò Àlàáfíà” 60
APÁ 3—“Àwọn Èèyàn Orílẹ̀-Èdè . . . Gba Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run”
9. “Ọlọ́run Kì Í Ṣe Ojúsàájú” 69
10. “Ọ̀rọ̀ Jèhófà Ń Gbilẹ̀” 77
APÁ 4—‘Ẹ̀mí Mímọ́ Rán Wọn Jáde’
11. Wọ́n ní “Ìdùnnú àti Ẹ̀mí Mímọ́ ní Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́” 85
12. Wọ́n “Fi Ìgboyà Sọ̀rọ̀ Nípasẹ̀ Àṣẹ Jèhófà” 93
APÁ 5—“Àwọn Àpọ́sítélì àti Àwọn Alàgbà Kóra Jọ”
13. ‘Lẹ́yìn Tí Wọ́n Jiyàn Díẹ̀’ 101
APÁ 6—“Ní Báyìí, Jẹ́ Ká Pa Dà Lọ Bẹ Àwọn Ará Wò”
15. Pọ́ọ̀lù “Ń Fún Àwọn Ìjọ Lókun” 117
16. “Sọdá Wá sí Makedóníà” 125
17. ‘Ó Bá Wọn Fèròwérò Látinú Ìwé Mímọ́’ 133
18. ‘Ẹ Wá Ọlọ́run, Kẹ́ Ẹ sì Rí I Ní Ti Gidi’ 140
19. “Máa Sọ̀rọ̀ Nìṣó, Má sì Dákẹ́” 148
APÁ 7—Wọ́n Ń Kọ́ni “ní Gbangba àti Láti Ilé dé Ilé”
20. “Ọ̀rọ̀ Jèhófà Ń Gbilẹ̀ Nìṣó, Ó sì Ń Borí” Lójú Àtakò 157
21. “Ọrùn Mi Mọ́ Kúrò Nínú Ẹ̀jẹ̀ Gbogbo Èèyàn” 165
APÁ 8—‘Wọ́n Wàásù Ìjọba Ọlọ́run Láìsí Ìdíwọ́’
23. “Ẹ Gbọ́ Ẹjọ́ Tí Mo Fẹ́ Rò fún Yín” 181
25. “Mo Ké Gbàjarè sí Késárì!” 196
26. “Kò sí Ìkankan Lára Yín Tó Máa Ṣègbé” 203