Ó yẹ kí ọ̀rọ̀ ẹni tó ń gbani nímọ̀ràn máa gbéni ró
16:4, 5
Ìrònú dorí Jóòbù kodò, ó sì ní ẹ̀dùn ọkàn, torí náà ó nílò ìtùnú àti ìṣírí
Àwọn ọ̀rẹ́ Jóòbù mẹ́tẹ̀ẹ̀ta kò tù ú nínú. Kàkà bẹ́ẹ̀, ṣe ni wọ́n ń dá a lẹ́bi tí wọ́n sì dá kún ìṣòro rẹ̀
Ọ̀rọ̀ kòbákùngbé tí Bílídádì sọ sí Jóòbù mú kí Jóòbù fi ìbínú sọ̀rọ̀
19:2, 25
Jóòbù bẹ Ọlọ́run pé kó jẹ́ kí òun kú kí ara lè tu òun
Jóòbù pọkàn pọ̀ sórí ìrètí àjíǹde, ó sì fara dàá délẹ̀délẹ̀