ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Báwo Ló Ṣe Yẹ Ká Máa Gbàdúrà sí Ọlọ́run?
    Jí!—2012 | April
    • Jésù sọ pé: “Nítorí náà, kí ẹ máa gbàdúrà ní ọ̀nà yìí: ‘Baba wa tí ń bẹ ní ọ̀run, kí orúkọ rẹ di sísọ di mímọ́. Kí ìjọba rẹ dé. Kí ìfẹ́ rẹ ṣẹ, gẹ́gẹ́ bí ti ọ̀run, lórí ilẹ̀ ayé pẹ̀lú. Fún wa lónìí oúnjẹ wa fún ọjọ́ òní; kí o sì dárí àwọn gbèsè wa jì wá, gẹ́gẹ́ bí àwa pẹ̀lú ti dárí ji àwọn ajigbèsè wa. Má sì mú wa wá sínú ìdẹwò, ṣùgbọ́n dá wa nídè kúrò lọ́wọ́ ẹni burúkú náà.’”—Mátíù 6:9-13.

  • Báwo Ló Ṣe Yẹ Ká Máa Gbàdúrà sí Ọlọ́run?
    Jí!—2012 | April
    • “Fún wa lónìí oúnjẹ wa fún ọjọ́ òní.” Lẹ́yìn tí Jésù ti sọ̀rọ̀ nípa orúkọ Ọlọ́run àti Ìjọba Ọlọ́run, ó ṣẹ̀sẹ̀ wá sọ̀rọ̀ nípa àwọn ohun tá a nílò. Àwọn ọ̀rọ̀ Jésù jẹ́ ká mọ̀ pé kò sídìí láti máa ṣe kìràkìtà kọjá ohun tá a nílò “fún ọjọ́ òní.” Kàkà bẹ́ẹ̀, ìmọ̀ràn tó wà nínú Òwe 30:8 ló yẹ ká fi sílò, ó sọ pé: “Má ṣe fún mi ní ipò òṣì tàbí ti ọrọ̀. Jẹ́ kí n jẹ ìwọ̀n oúnjẹ tí ó jẹ́ ìpín tèmi.”

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́