-
Ìdí Tá A Fi Ń Wá Síbi Ìrántí Ikú KristiIlé Ìṣọ́ (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2022 | January
-
-
2 Lọ́dọọdún, a máa ń dara pọ̀ mọ́ ọ̀pọ̀ mílíọ̀nù èèyàn kárí ayé láti ṣe Ìrántí Ikú Kristi ní àyájọ́ ọjọ́ tó kú torí pé a nífẹ̀ẹ́ rẹ̀. (1 Pét. 1:8) A máa ń pé jọ láti ṣe Ìrántí Ikú ẹni tó fi ẹ̀mí rẹ̀ rà wá pa dà kó lè gbà wá sílẹ̀ lọ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ àti ikú. (Mát. 20:28) Kódà, Jésù fẹ́ káwa ọmọlẹ́yìn rẹ̀ máa ṣe Ìrántí Ikú òun. Ní alẹ́ tó ṣáájú ọjọ́ tí Jésù kú, ó dá Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa sílẹ̀, ó sì pàṣẹ pé: “Ẹ máa ṣe èyí ní ìrántí mi.”—Lúùkù 22:19.
-
-
Ìdí Tá A Fi Ń Wá Síbi Ìrántí Ikú KristiIlé Ìṣọ́ (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2022 | January
-
-
b Kó o lè mọ̀ sí i nípa májẹ̀mú tuntun àti májẹ̀mú Ìjọba, wo àpilẹ̀kọ náà, “Ẹ̀yin Yóò Di ‘Ìjọba Àwọn Àlùfáà’” nínú Ilé Ìṣọ́ October 15, 2014, ojú ìwé 15-17.
-