-
Jerúsálẹ́mù àti Tẹ́ńpìlì Tí Jésù Bá LáyéWo “Ilẹ̀ Dáradára” Náà
-
-
Ní apá àríwá tẹ́ńpìlì náà, níbi odò adágún Bẹtisátà, Jésù mú ọkùnrin kan tó ti jìyà fún ọdún méjìdínlógójì lára dá. Ọmọ Ọlọ́run tún la ojú afọ́jú kan, nípa sísọ fún un pé kó lọ wẹ̀ nínú odò adágún Sílóámù ní apá ìhà gúúsù ìlú náà.—Jo 5:1-15; 9:1, 7, 11.
-
-
Jerúsálẹ́mù àti Tẹ́ńpìlì Tí Jésù Bá LáyéWo “Ilẹ̀ Dáradára” Náà
-
-
ÀFONÍFOJÌ KÍDÍRÓNÌ
-