ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Onínúnibíni Rí Ìmọ́lẹ̀ Ńlá
    Ilé Ìṣọ́—2000 | January 15
    • Júdásì, tó ń gbé ní ojú pópó tí a ń pè ní Títọ́, gba Sọ́ọ̀lù lálejò.a (Ìṣe 9:11) Ojú pópó yìí—tí a ń pè ní Darb al-Mustaqim ní èdè Lárúbáwá—ṣì jẹ́ ojú ọ̀nà kan ní Damásíkù títí di òní olónìí. Fojú inú wo ohun tí Sọ́ọ̀lù lè máa rò nígbà tó wà nílé Júdásì. Ìrírí tí Sọ́ọ̀lù ní yìí ti fọ́ ọ lójú, ó sì ti kó jìnnìjìnnì bá a. Àkókò wá wà fún un wàyí láti ronú lórí ohun tí ìṣẹ̀lẹ̀ yẹn túmọ̀ sí.

  • Onínúnibíni Rí Ìmọ́lẹ̀ Ńlá
    Ilé Ìṣọ́—2000 | January 15
    • a Ọ̀mọ̀wé akẹ́kọ̀ọ́jinlẹ̀ kan rò pé Júdásì ní láti jẹ́ aṣáájú àwùjọ àwọn Júù tó wà ládùúgbò náà tàbí kó jẹ́ pé ó ní ilé èrò kan tí àwọn Júù lè dé sí.

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́