-
“Ọlọ́gbọ́n Ni”—Síbẹ̀ Ó Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀Sún Mọ́ Jèhófà
-
-
7 Síbẹ̀, onírẹ̀lẹ̀ ni Jèhófà, ó sì níwà tútù. Ó kọ́ àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pé tí wọ́n bá fẹ́ ní ọgbọ́n tòótọ́, wọ́n gbọ́dọ̀ jẹ́ oníwà tútù. Ọ̀rọ̀ rẹ̀ sọ nípa ẹni tó “fi ìwà tútù ṣe àwọn iṣẹ́ tó fi hàn pé ó gbọ́n.”b (Jémíìsì 3:13) Ẹ jẹ́ ká wo àpẹẹrẹ Jèhófà.
-
-
“Ọlọ́gbọ́n Ni”—Síbẹ̀ Ó Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀Sún Mọ́ Jèhófà
-
-
b Àwọn ìtúmọ̀ Bíbélì míì pè é ní “ìwà tútù ti ọgbọ́n” àti “ìwà ìrẹ̀lẹ̀ tí ó fi ọgbọ́n hàn.”
-