-
Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn ÒǹkàwéIlé Ìṣọ́—2014 | November 15
-
-
Nígbà tí àkókò tí wọ́n fi wàásù nínú aṣọ àpò ìdọ̀họ náà parí, wọ́n pa àwọn ẹni àmì òróró náà lọ́nà ìṣàpẹẹrẹ nígbà tí wọ́n jù wọ́n sẹ́wọ̀n fún àkókò kúkúrú, èyí tó dúró fún ọjọ́ mẹ́ta àti ààbọ̀. Lójú àwọn ọ̀tá àwọn èèyàn Ọlọ́run yìí, ńṣe ló dà bíi pé wọ́n ti pa iṣẹ́ àwọn ẹlẹ́rìí méjì náà run, èyí sì mú inú àwọn ọ̀tá náà dùn gan-an.—Ìṣí. 11:8-10.
-