B14-B
Owó àti Ìdíwọ̀n
Owó àti Ìdíwọ̀n Nínú Ìwé Mímọ́ Lédè Hébérù
Gérà (Ṣékélì 1⁄20)
Gíráàmù 0.57 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 0.01835
Gérà 10 = Bíkà 1
Bíkà
Gíráàmù 5.7 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 0.1835
Bíkà 2 = Ṣékélì 1
Píìmù
Gíráàmù 7.8 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 0.2508
Píìmù 1 = Ṣékélì 2⁄3
Ìdíwọ̀n ṣékélì
Ṣékélì
Gíráàmù 11.4 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 0.367
Ṣékélì 50 = Mínà 1
Mínà
Gíráàmù 570 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 18.35
Mínà 60 = Tálẹ́ńtì 1
Tálẹ́ńtì
Kìlógíráàmù 34.2 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 1,101
Owó àti Ìdíwọ̀n Nínú Ìwé Mímọ́ Kristẹni Lédè Gíríìkì
Dínárì
(Ti àwọn Róòmù, fàdákà)
Kúádíránì 64
Gíráàmù 3.85 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 0.124
= Owó Iṣẹ́ Ọjọ́ 1 (Wákàtí 12)
Dírákímà
(Ti àwọn Gíríìkì, fàdákà)
Gíráàmù 3.4 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 0.109
= Owó Iṣẹ́ Ọjọ́ 1 (12 hours)
Dírákímà méjì alápapọ̀
(Ti àwọn Gíríìkì, fàdákà)
Dírákímà 2
Gíráàmù 6.8 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 0.218
= Owó Iṣẹ́ Ọjọ́ 2
Dírákímà mẹ́rin alápapọ̀ ti Tírè (Ṣékélì fàdákà ti Tírè)
Dírákímà mẹ́rin alápapọ̀
(Ti àwọn Gíríìkì, fàdákà; wọ́n tún ń pè é ní owó sítátà fàdákà)
Dírákímà 4
Gíráàmù 13.6 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 0.436
= Owó Iṣẹ́ Ọjọ́ 4
Tálẹ́ńtì
Mínà 60
Kìlógíráàmù 20.4 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 654
= nǹkan bí owó iṣẹ́ 20 ọdún
Ìwọ̀n Pọ́n-ùn (ti àwọn ará Róòmù)
Gíráàmù 327 / Ọ́ǹsì 11.5
“Ìwọ̀n pọ́n-ùn kan òróró onílọ́fínńdà, ojúlówó náádì”