Sáàmù Orin Ìgòkè. 134 Ẹ yin Jèhófà,Gbogbo ẹ̀yin ìránṣẹ́ Jèhófà,+Ẹ̀yin tó ń ṣiṣẹ́ nínú ilé Jèhófà ní òròòru.+ 2 Ẹ gbé ọwọ́ yín sókè+ nínú ìjẹ́mímọ́,*Kí ẹ sì yin Jèhófà. 3 Kí Jèhófà, Aṣẹ̀dá ọ̀run àti ayé,Bù kún ọ láti Síónì.