-
Jẹ́nẹ́sísì 43:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Kí Ọlọ́run Olódùmarè mú kí ọkùnrin náà ṣàánú yín, kó lè fi arákùnrin yín kan tó kù àti Bẹ́ńjámínì sílẹ̀. Àmọ́ ní tèmi, tó bá jẹ́ pé ọ̀fọ̀ yóò ṣẹ̀ mí+ lóòótọ́, kó ṣẹ̀ mí!”
-