Jẹ́nẹ́sísì 42:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Jékọ́bù bàbá wọn wá sọ fún wọn pé: “Èmi ni ẹ mú kí ọ̀fọ̀ ṣẹ̀!+ Jósẹ́fù ò sí mọ́,+ Síméónì náà ò sí mọ́,+ ẹ tún fẹ́ mú Bẹ́ńjámínì lọ! Èmi ni gbogbo nǹkan yìí wá ṣẹlẹ̀ sí!”
36 Jékọ́bù bàbá wọn wá sọ fún wọn pé: “Èmi ni ẹ mú kí ọ̀fọ̀ ṣẹ̀!+ Jósẹ́fù ò sí mọ́,+ Síméónì náà ò sí mọ́,+ ẹ tún fẹ́ mú Bẹ́ńjámínì lọ! Èmi ni gbogbo nǹkan yìí wá ṣẹlẹ̀ sí!”