Jẹ́nẹ́sísì 47:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Jékọ́bù sọ fún Fáráò pé: “Àádóje (130) ọdún ni mo fi ń lọ káàkiri.* Ọdún tí mo ti lò láyé kéré, ó sì kún fún wàhálà,+ kò gùn tó ọdún tí àwọn baba ńlá mi lò láyé nígbà tí wọ́n ń lọ káàkiri.”*+
9 Jékọ́bù sọ fún Fáráò pé: “Àádóje (130) ọdún ni mo fi ń lọ káàkiri.* Ọdún tí mo ti lò láyé kéré, ó sì kún fún wàhálà,+ kò gùn tó ọdún tí àwọn baba ńlá mi lò láyé nígbà tí wọ́n ń lọ káàkiri.”*+