11 Ísírẹ́lì bàbá wọn wá sọ fún wọn pé: “Tọ́rọ̀ bá rí bẹ́ẹ̀, ohun tí ẹ máa ṣe nìyí: Ẹ kó àwọn ohun tó dáa jù ní ilẹ̀ yìí sínú àwọn àpò yín, kí ẹ gbé e lọ fún ọkùnrin náà bí ẹ̀bùn:+ básámù+ díẹ̀, oyin díẹ̀, gọ́ọ̀mù lábídánọ́mù, èèpo+ igi olóje, ẹ̀pà pítáṣíò àti álímọ́ńdì.