Ẹ́kísódù 29:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Kí o wá kó àwọn aṣọ náà,+ kí o sì wọ aṣọ àwọ̀tẹ́lẹ̀ fún Áárónì, pẹ̀lú aṣọ àwọ̀lékè tí kò lápá tó máa wà lábẹ́ éfódì, kí o wọ éfódì náà fún un àti aṣọ ìgbàyà, kí o sì so àmùrè éfódì tí wọ́n hun* náà mọ́ ìbàdí rẹ̀ pinpin.+
5 Kí o wá kó àwọn aṣọ náà,+ kí o sì wọ aṣọ àwọ̀tẹ́lẹ̀ fún Áárónì, pẹ̀lú aṣọ àwọ̀lékè tí kò lápá tó máa wà lábẹ́ éfódì, kí o wọ éfódì náà fún un àti aṣọ ìgbàyà, kí o sì so àmùrè éfódì tí wọ́n hun* náà mọ́ ìbàdí rẹ̀ pinpin.+