Ẹ́kísódù 5:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àmọ́ Fáráò sọ pé: “Ta ni Jèhófà,+ tí màá fi gbọ́ràn sí i lẹ́nu pé kí n jẹ́ kí Ísírẹ́lì lọ?+ Mi ò mọ Jèhófà rárá, mi ò sì ní jẹ́ kí Ísírẹ́lì lọ.”+
2 Àmọ́ Fáráò sọ pé: “Ta ni Jèhófà,+ tí màá fi gbọ́ràn sí i lẹ́nu pé kí n jẹ́ kí Ísírẹ́lì lọ?+ Mi ò mọ Jèhófà rárá, mi ò sì ní jẹ́ kí Ísírẹ́lì lọ.”+