-
Ẹ́kísódù 16:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Ní ọjọ́ kẹfà, wọ́n kó ìlọ́po méjì oúnjẹ náà,+ oúnjẹ tó kún òṣùwọ̀n ómérì méjì fún ẹnì kan. Gbogbo ìjòyè àpéjọ náà wá sọ ohun tó ń ṣẹlẹ̀ fún Mósè.
-