Ẹ́kísódù 16:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àmọ́ ní ọjọ́ kẹfà,+ nígbà tí wọ́n bá ń ṣètò ohun tí wọ́n kó, kó jẹ́ ìlọ́po méjì ohun tí wọ́n ń kó ní àwọn ọjọ́ tó kù.”+
5 Àmọ́ ní ọjọ́ kẹfà,+ nígbà tí wọ́n bá ń ṣètò ohun tí wọ́n kó, kó jẹ́ ìlọ́po méjì ohun tí wọ́n ń kó ní àwọn ọjọ́ tó kù.”+