30 Níkẹyìn, wọ́n fi ògidì wúrà ṣe irin pẹlẹbẹ tó ń dán, tó jẹ́ àmì mímọ́ ti ìyàsímímọ́,* wọ́n sì fín ọ̀rọ̀ sára rẹ̀ bí ẹni fín èdìdì, pé: “Ìjẹ́mímọ́ jẹ́ ti Jèhófà.”+
9 Lẹ́yìn náà, ó wé láwàní+ sí i lórí, ó sì fi irin wúrà pẹlẹbẹ tó ń dán tó jẹ́ àmì mímọ́ ti ìyàsímímọ́*+ sí iwájú láwàní náà, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún Mósè.