-
Léfítíkù 4:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Kó gbé ọwọ́ rẹ̀ lé orí ọmọ ewúrẹ́ náà, kó sì pa á níbi tí wọ́n ti ń pa ẹran ẹbọ sísun níwájú Jèhófà.+ Ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ ni.
-
-
Léfítíkù 4:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Kó mú kí gbogbo ọ̀rá rẹ̀ rú èéfín lórí pẹpẹ bí ọ̀rá ẹbọ ìrẹ́pọ̀;+ àlùfáà yóò sì ṣe ètùtù fún un torí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, yóò sì rí ìdáríjì.
-