-
Ẹ́kísódù 32:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Ní ọjọ́ kejì, Mósè sọ fún àwọn èèyàn náà pé: “Ẹ̀ṣẹ̀ ńlá lẹ dá, màá sì gòkè tọ Jèhófà lọ báyìí, kí n wò ó bóyá mo lè bá yín wá nǹkan ṣe sí ẹ̀ṣẹ̀ tí ẹ dá.”+
-
-
Nọ́ńbà 15:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Kí àlùfáà ṣe ètùtù fún gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, wọ́n á sì rí ìdáríjì,+ torí pé àṣìṣe ni, wọ́n ti mú ọrẹ àfinásun wá fún Jèhófà, wọ́n sì ti mú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ wọn wá síwájú Jèhófà nítorí àṣìṣe wọn.
-