Ẹ́kísódù 25:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Kí ẹ ṣe àgọ́ ìjọsìn àti gbogbo ohun tó máa wà níbẹ̀, kó rí bí ohun* tí màá fi hàn ọ́ gẹ́lẹ́.+ Ẹ́kísódù 25:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Rí i pé o ṣe wọ́n bí ohun* tí mo fi hàn ọ́ lórí òkè.+ 1 Kíróníkà 28:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ó fún un ní àwòrán ìkọ́lé gbogbo ohun tí a fi hàn án nípa ìmísí* nípa àwọn àgbàlá+ ilé Jèhófà, ti gbogbo àwọn yàrá ìjẹun tó yí i ká, ti àwọn ibi ìṣúra ilé Ọlọ́run tòótọ́ àti ti àwọn ibi ìṣúra tí wọ́n ń kó àwọn ohun tí a sọ di* mímọ́+ sí; 1 Kíróníkà 28:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Dáfídì sọ pé: “Ọwọ́ Jèhófà wà pẹ̀lú mi, ó sì fún mi ní ìjìnlẹ̀ òye kí n lè kọ+ gbogbo kúlẹ̀kúlẹ̀ àwòrán ìkọ́lé+ náà sílẹ̀.”
12 Ó fún un ní àwòrán ìkọ́lé gbogbo ohun tí a fi hàn án nípa ìmísí* nípa àwọn àgbàlá+ ilé Jèhófà, ti gbogbo àwọn yàrá ìjẹun tó yí i ká, ti àwọn ibi ìṣúra ilé Ọlọ́run tòótọ́ àti ti àwọn ibi ìṣúra tí wọ́n ń kó àwọn ohun tí a sọ di* mímọ́+ sí;
19 Dáfídì sọ pé: “Ọwọ́ Jèhófà wà pẹ̀lú mi, ó sì fún mi ní ìjìnlẹ̀ òye kí n lè kọ+ gbogbo kúlẹ̀kúlẹ̀ àwòrán ìkọ́lé+ náà sílẹ̀.”