Diutarónómì 16:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Kí o fi ẹran Ìrékọjá rúbọ sí Jèhófà Ọlọ́run rẹ,+ látinú agbo ẹran àti ọ̀wọ́ ẹran,+ ní ibi tí Jèhófà yàn pé kí orúkọ rẹ̀ máa wà.+ Diutarónómì 26:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 kí o mú lára gbogbo ohun* tó bá kọ́kọ́ so ní ilẹ̀ náà, èyí tí o bá kó jọ ní ilẹ̀ rẹ tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ fẹ́ fún ọ, kí o kó o sínú apẹ̀rẹ̀, kí o sì lọ sí ibi tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ bá yàn pé kí orúkọ rẹ̀ máa wà.+
2 Kí o fi ẹran Ìrékọjá rúbọ sí Jèhófà Ọlọ́run rẹ,+ látinú agbo ẹran àti ọ̀wọ́ ẹran,+ ní ibi tí Jèhófà yàn pé kí orúkọ rẹ̀ máa wà.+
2 kí o mú lára gbogbo ohun* tó bá kọ́kọ́ so ní ilẹ̀ náà, èyí tí o bá kó jọ ní ilẹ̀ rẹ tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ fẹ́ fún ọ, kí o kó o sínú apẹ̀rẹ̀, kí o sì lọ sí ibi tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ bá yàn pé kí orúkọ rẹ̀ máa wà.+