-
Jóṣúà 4:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kìíní, àwọn èèyàn náà kúrò ní Jọ́dánì, wọ́n sì pàgọ́ sí Gílígálì+ ní ààlà Jẹ́ríkò lápá ìlà oòrùn.
-
-
Jóṣúà 10:43Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
43 Lẹ́yìn náà, Jóṣúà àti gbogbo Ísírẹ́lì pa dà sí ibùdó ní Gílígálì.+
-