-
Jóṣúà 19:48Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
48 Èyí ni ogún ẹ̀yà Dánì ní ìdílé-ìdílé. Èyí sì ni àwọn ìlú náà pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn.
-
-
Àwọn Onídàájọ́ 14:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Sámúsìn sọ̀ kalẹ̀ lọ sí Tímúnà, ó sì rí obìnrin Filísínì* kan ní Tímúnà. 2 Ó wá lọ sọ fún bàbá àti ìyá rẹ̀ pé: “Mo rí obìnrin Filísínì kan ní Tímúnà, mo sì fẹ́ kí ẹ fẹ́ ẹ fún mi kí n fi ṣe aya.”
-