16Ilẹ̀ tí wọ́n fi kèké pín*+ fún àwọn àtọmọdọ́mọ Jósẹ́fù+ bẹ̀rẹ̀ láti Jọ́dánì ní Jẹ́ríkò dé ibi omi tó wà lápá ìlà oòrùn Jẹ́ríkò, ó gba inú aginjù láti Jẹ́ríkò lọ sí agbègbè olókè Bẹ́tẹ́lì.+
13 Ààlà náà tún lọ láti ibẹ̀ dé Lúsì, ní gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ tó wà lápá gúúsù Lúsì, ìyẹn Bẹ́tẹ́lì;+ ààlà náà dé Ataroti-ádárì+ lórí òkè tó wà ní gúúsù Bẹti-hórónì Ìsàlẹ̀.+