-
Jóṣúà 19:47, 48Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
47 Àmọ́ ilẹ̀ Dánì ti kéré jù fún wọn.+ Torí náà, wọ́n lọ bá Léṣémù + jà, wọ́n gbà á, wọ́n sì fi idà ṣá wọn balẹ̀. Ó di tiwọn, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í gbé ibẹ̀, wọ́n wá yí orúkọ Léṣémù pa dà sí Dánì, ìyẹn Dánì tó jẹ́ orúkọ baba ńlá wọn.+ 48 Èyí ni ogún ẹ̀yà Dánì ní ìdílé-ìdílé. Èyí sì ni àwọn ìlú náà pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn.
-
-
1 Àwọn Ọba 4:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Júdà àti Ísírẹ́lì ń gbé lábẹ́ ààbò ní gbogbo ọjọ́ ayé Sólómọ́nì, kálukú lábẹ́ àjàrà rẹ̀ àti lábẹ́ igi ọ̀pọ̀tọ́ rẹ̀, láti Dánì títí dé Bíá-ṣébà.
-