-
Jóṣúà 4:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Jóṣúà tún to òkúta méjìlá (12) sí àárín Jọ́dánì níbi tí àwọn àlùfáà tí wọ́n gbé àpótí májẹ̀mú náà dúró sí,+ àwọn òkúta náà sì wà níbẹ̀ títí dòní.
-